Onídájọ́ 6:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láìpẹ́ jọjọ àwọn ogun àwọn Mídíánì, ti àwọn Ámálékì àti ti àwọn ènìyàn ìhà ìlà oòrùn yóòkù kó ara wọn jọ pọ̀ ní ìṣọ̀kan, wọ́n sì kọjá Jọ́dánì wọ́n sì tẹ̀dó sí àfonífojì Jésírẹ́lì.

Onídájọ́ 6

Onídájọ́ 6:24-36