Onídájọ́ 6:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jọ̀wọ́ má ṣe kúrò níbí títí èmi yóò fi mú ọrẹ wá fún ọ kí n sì gbé e sí iwájú rẹ. Olúwa sì wí pé, “Èmi yóò dúró títí ìwọ yóò fi dé.”

Onídájọ́ 6

Onídájọ́ 6:14-22