Onídájọ́ 5:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní àwọn ọjọ́ Ṣámgárì ọmọ Ánátì,Ní àwọn ọjọ́ Jáélì, a kọ àwọn ojú ọ̀nà sílẹ̀;àwọn arìnrìnàjò ń gba kọ̀rọ̀ kọ́rọ́.

Onídájọ́ 5

Onídájọ́ 5:1-12