Onídájọ́ 5:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa nígbà tí o jáde lọ láti Ṣéírì,nígbà tí o yan láti ilẹ̀ Édómù,ilẹ̀ mì tìtì, àwọn ọ̀run ya,ìkúùkù àwọ̀sámọ̀ da omi wọn sílẹ̀.

Onídájọ́ 5

Onídájọ́ 5:3-10