Onídájọ́ 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bárákì sì dá a lóhùn pé, “Èmi yóò lọ tí ìwọ ó bá bá mi lọ, ṣùgbọ́n tí ìwọ kì yóò bá bá mi lọ, èmi kì yóò lọ.”

Onídájọ́ 4

Onídájọ́ 4:2-13