Onídájọ́ 3:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní báyìí, wọ́n ti pa tó ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ọkùnrin ará Móábù tí wọ́n jẹ́ alágbára àti onígboyà ènìyàn, kò sí ènìyàn tí ó sálà.

Onídájọ́ 3

Onídájọ́ 3:19-31