Onídájọ́ 21:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báwo ni a ó ò ṣe rí aya fún àwọn tí ó ṣẹ́kù, nítorí àwa ti fi Olúwa búra láti má fi ọ̀kankan nínú àwọn ọmọbìnrin wa fún wọn ní aya.

Onídájọ́ 21

Onídájọ́ 21:1-10