Onídájọ́ 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa gbé àwọn onídájọ́ (aṣíwájú tí ó ní agbára) dìde sí àwọn tí ó gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ọ̀ta wọn.

Onídájọ́ 2

Onídájọ́ 2:14-22