Onídájọ́ 19:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àna rẹ̀, baba ọmọbìnrin náà rọ̀ ọ́, ó sì borí rẹ̀ láti dá a dúró fún ìgbà díẹ̀, òun sì dúró fún ọjọ́ mẹ́ta, ó ń jẹ, ó ń mu, ó sì ń sùn níbẹ̀.

Onídájọ́ 19

Onídájọ́ 19:1-8