Onídájọ́ 19:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀gá rẹ̀ dá a lóhùn pé, “Rárá o, àwa kì yóò wọ ìlú àwọn àjèjì, àwọn tí olùgbé ibẹ̀ kì í ṣe ọmọ Ísírẹ́lì, a ó ò dé Gíbíà.”

Onídájọ́ 19

Onídájọ́ 19:8-20