Onídájọ́ 18:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n wí fún un pé, “Jọ̀wọ́ béèrè ní ọwọ́ Ọlọ́run, kí àwa lè mọ̀ bí ìrìnàjò wa yóò yọrí sí rere.”

Onídájọ́ 18

Onídájọ́ 18:1-12