Onídájọ́ 18:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ibẹ̀ wọ́n kọjá lọ sí àwọn ìlú agbègbè òkè Éfúráímù, wọ́n sì dé ilé Míkà.

Onídájọ́ 18

Onídájọ́ 18:5-14