Onídájọ́ 16:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun dáhùn pé, “Bí wọ́n bá lè fi okùn túntún tí ẹnikẹ́ni kò tíì lò rí dì mí dáadáa, èmi yóò di aláìlágbára, èmì yóò sì dàbí àwọn ọkùnrin yóòkù.”

Onídájọ́ 16

Onídájọ́ 16:3-17