Onídájọ́ 15:15-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Nígbà tí ó rí egungun àgbọ̀n ìṣàlẹ̀ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ túntún kan, ó mú un, ó sì fi pa ẹgbẹ̀rún ọkùnrin.

16. Sámúsónì sì wí pé,“Pẹ̀lú egungun àgbọ̀n ìsàlẹ̀ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kanMo sọ wọ́n di òkìtì kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.Pẹ̀lú egungun àgbọ̀n ìsàlẹ̀ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kanMo ti pa ẹgbẹ̀rún ọkùnrin.”

17. Nígbà tí ó dákẹ́ ọ̀rọ̀ ísọ, ó ju egungun àgbọ̀n ìṣàlẹ̀ náà nù, wọ́n sì pe ibẹ̀ ní Ramati-Léhì (ìtúmọ̀ rẹ̀ jẹ́ egungun àgbọ̀n ìṣàlẹ̀ pa).

Onídájọ́ 15