Onídájọ́ 13:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mánóà sọ fún aya rẹ̀ pé, “Dájúdájú àwa yóò kú nítorí àwa ti fi ojú rí Ọlọ́run.”

Onídájọ́ 13

Onídájọ́ 13:16-23