Onídájọ́ 13:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mánóà bi ọkùnrin náà pé, “Nígbà tí ọ̀rọ̀ rẹ bá ṣẹ kí ni yóò jẹ́ ìlànà fún ìgbé ayé àti iṣẹ́ ọmọ náà?”

Onídájọ́ 13

Onídájọ́ 13:2-14