Onídájọ́ 11:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́fità dáhùn pé, “Bí ẹ̀yin bá mú mi padà láti bá àwọn ará Ámónì jà àti tí Olúwa bá fi wọ́n lé mi lọ́wọ́: ṣe èmi yóò jẹ́ olórí yín nítòótọ́.”

Onídájọ́ 11

Onídájọ́ 11:1-12