Onídájọ́ 10:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó bínú sí wọn, ó fi wọ́n sílẹ̀ fún àwọn ará Fílístínì àti Ámónì láti jẹ ẹ́ ní ìyà.

Onídájọ́ 10

Onídájọ́ 10:6-17