Onídájọ́ 10:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jáírì ti ẹ̀yà Gílíádì ni ó dìde lẹ́yìn rẹ̀, ó ṣàkóso Ísirẹ́lì ní ọdún méjìlélógún.

Onídájọ́ 10

Onídájọ́ 10:1-12