Onídájọ́ 10:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíbẹ̀ṣíbẹ̀ ẹ̀yin kọ̀ mí sílẹ̀ láti sin àwọn ọlọ́run mìíràn, torí ìdí èyí, èmi kì yóò sì tún gbà yín mọ́.

Onídájọ́ 10

Onídájọ́ 10:9-15