Onídájọ́ 1:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààlà àwọn ará Ámórì sì bẹ̀rẹ̀ láti ìgòkè Ákírábímù kọjá lọ sí Ṣélà àti síwájú sí i.

Onídájọ́ 1

Onídájọ́ 1:28-36