Onídájọ́ 1:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Éfúráímù náà kò lé àwọn ará Kénánì tí ó ń gbé Géṣérì jáde, ṣùgbọ́n àwọn ará Kénánì sì ń gbé láàrin àwọn ẹ̀yà Éfúráímù.

Onídájọ́ 1

Onídájọ́ 1:28-30