Ọbadáyà 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ kì bá tí dúró ní ìkóríta ọ̀nàláti ké àwọn tirẹ̀ tó ti sálà kúrò.Ìwọ kì bá tí fa àwọn tó sẹ́kùwọn lélẹ̀ ní ọjọ́ wàhálà wọn.

Ọbadáyà 1

Ọbadáyà 1:8-20