Nọ́ḿbà 9:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbá à ṣe fún ọjọ́ méjì, oṣù kan tàbí ọdún kan ni ìkúùkù fi dúró sórí àgọ́, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò dúró ní ibùdó wọn, wọn ò ní í gbéra; ṣùgbọ́n nígbà tí ó bá lọ sókè ni wọn ó tó o gbéra.

Nọ́ḿbà 9

Nọ́ḿbà 9:21-23