Nọ́ḿbà 9:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa àṣẹ Olúwa ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń jáde lọ, nípa àṣẹ Olúwa náà sì ni wọ́n ń pa ibùdó wọn. Nígbà tí ìkúùkù bá dúró sórí àgọ́, àwọn náà yóò dúró sí ibùdó.

Nọ́ḿbà 9

Nọ́ḿbà 9:11-23