Nọ́ḿbà 9:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbàkígbà tí ìkúùkù yìí bá ká sókè kúrò lórí àgọ́ ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò dìde láti máa lọ; ibikíbi tí ìkúùkù náà bá dúró sí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò pa ibùdó wọn sí.

Nọ́ḿbà 9

Nọ́ḿbà 9:12-19