Nọ́ḿbà 8:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè, Árónì àti gbogbo ìjọ ènìyàn Ísírẹ́lì sì ṣe fún àwọn ọmọ Léfì gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mósè.

Nọ́ḿbà 8

Nọ́ḿbà 8:14-22