Nọ́ḿbà 8:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì yóò sì mú àwọn ọmọ Léfì wá ṣíwájú Olúwa gẹ́gẹ́ bí ọrẹ fífì láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá, kí wọn lè máa ṣiṣẹ́ Olúwa.

Nọ́ḿbà 8

Nọ́ḿbà 8:2-17