Nọ́ḿbà 8:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni kí o mú àwọn ọmọ Léfì wá ṣíwájú Olúwa, gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì yóò sì gbọ́wọ́ lé àwọn ọmọ Léfì lórí.

Nọ́ḿbà 8

Nọ́ḿbà 8:4-15