Nọ́ḿbà 7:85 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwo fàdákà kọ̀ọ̀kan wọn àádóje (130) ṣékélì, àwokòtò kọ̀ọ̀kan sì wọn àádọ́rin (70). Àpapọ̀ gbogbo àwo fàdákà jẹ́ egbèjìlá ṣékélì (2,400) gẹ́gẹ́ bí iye owó ibi mímọ́.

Nọ́ḿbà 7

Nọ́ḿbà 7:78-89