Màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-ún àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún, tí wọn ó fí rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Págíélì ọmọ Ókíránì.