Nọ́ḿbà 7:65 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-ún àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Ábídánì ọmọ Gídíónì.

Nọ́ḿbà 7

Nọ́ḿbà 7:56-70