Nọ́ḿbà 7:59 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-ún àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Gámálíélì ọmọ Pédásúrì.

Nọ́ḿbà 7

Nọ́ḿbà 7:55-65