Nọ́ḿbà 7:54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gàmálíèlì ọmọ Pédáṣúrì, olórí àwọn ọmọ Mánásè ni ó mú ọrẹ tirẹ̀ wá ní ọjọ́ kẹjọ.

Nọ́ḿbà 7

Nọ́ḿbà 7:53-61