Nọ́ḿbà 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gba gbogbo nǹkan wọ̀nyí lọ́wọ́ wọn, kí wọ́n ba à lè wúlò fún iṣẹ́ inú Àgọ́ Ìpàdé. Kó wọn fún àwọn ọmọ Léfì gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan bá ṣe nílò rẹ̀.”

Nọ́ḿbà 7

Nọ́ḿbà 7:1-11