Nọ́ḿbà 7:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-ún àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún, wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Eliásáfì ọmọ Déúélì.

Nọ́ḿbà 7

Nọ́ḿbà 7:41-50