Nọ́ḿbà 7:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Màlúù méjì, àgbò márùn ún, akọ àgùntàn ọlọ́dún kan márùn ún tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà. Wọ̀nyí ni ọrẹ Násónì ọmọ Ámínádábù.

Nọ́ḿbà 7

Nọ́ḿbà 7:13-21