Nọ́ḿbà 7:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí Olúwa ti sọ fún Mósè pé, “Olórí kọ̀ọ̀kan ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan ni yóò máa mú ọrẹ tirẹ̀ wá ṣíwájú pẹpẹ.”

Nọ́ḿbà 7

Nọ́ḿbà 7:8-13