Nọ́ḿbà 5:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tàbí nígbà tí ẹ̀mí owú jíjẹ bá bà lé ọkùnrin kan nítorí pé ó fura sí ìyàwó rẹ̀. Àlùfáà yóò mú obìnrin náà dúró níwájú Olúwa yóò sì ṣe gẹ́gẹ́ bí òfin ti wí fún un.

Nọ́ḿbà 5

Nọ́ḿbà 5:28-31