Nọ́ḿbà 5:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nígbà náà ni àlùfáà yóò mú obìnrin náà búra, yóò sọ fún obìnrin náà pé: “Kí Olúwa sọ ọ́ di ẹni ègún àti ẹni ìbáwí láàrin àwọn ènìyàn rẹ nípa mímú kí itan rẹ jẹrà, kí ikùn rẹ sì wú.

Nọ́ḿbà 5

Nọ́ḿbà 5:15-29