Nọ́ḿbà 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lórí gbogbo nǹkan wọ̀nyí ni wọn yóò da, wọn ó tún fi awọ ewúrẹ́ bò ó, wọn ó sì fi òpó rẹ̀ bọ ààyè rẹ̀.

Nọ́ḿbà 4

Nọ́ḿbà 4:1-9