Nọ́ḿbà 4:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni àpapọ̀ iye àwọn ọmọ Mérárì. Mósè àti Árónì kà wọ́n gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Olúwa láti ẹnu Mósè.

Nọ́ḿbà 4

Nọ́ḿbà 4:40-49