Nọ́ḿbà 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kí wọn kó gbogbo ohun èlò tí wọ́n ń lò fún iṣẹ́ ìsìn ní ibi mímọ́, kí wọn ó fi aṣọ aláwọ̀ búlúù yìí, kí wọn ó sì fi bò ó, kí wọn ó sì fi gbé wọn ka orí férémù.

Nọ́ḿbà 4

Nọ́ḿbà 4:7-21