Nọ́ḿbà 35:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mẹ́fà lára ìlú tí ẹ fún àwọn ọmọ Léfì yóò jẹ́ ìlú ibi ìsásí, tí ẹni tí ó bá pa ènìyàn yóò sá sí. Ní àfikún, ẹ fún wọn ní méjìlélógójì (42) ìlú sí i.

Nọ́ḿbà 35

Nọ́ḿbà 35:3-16