Nọ́ḿbà 35:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Má ṣe sọ ilẹ̀ tí ẹ wà di àìmọ́. Ìtàjẹ̀ sílẹ̀ sọ ilẹ̀ náà di àìmọ́. Atúnṣe kì yóò sí fún ilẹ̀ tí a ti ta ẹ̀jẹ̀ lé lórí, àyà fi ẹ̀jẹ̀ ẹni tí ó ta á sílẹ̀.

Nọ́ḿbà 35

Nọ́ḿbà 35:25-34