Nọ́ḿbà 35:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tàbí pẹ̀lú ìjà gbangba lù ú pẹ̀lú ìkúùkù tí ó sì kú, pípa ni a ó pa ẹni bẹ́ẹ̀; apànìyàn ni. Olùgbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ yóò pa apànìyàn náà tí ó bá bá a.

Nọ́ḿbà 35

Nọ́ḿbà 35:18-25