Nọ́ḿbà 35:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì láti fún àwọn Léfì ní ilẹ̀ láti gbé lára ogún tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò jogún. Kí ẹ sì fún wọn ní ilẹ̀ lára pápá oko tútù, káàkiri ìlú.

Nọ́ḿbà 35

Nọ́ḿbà 35:1-5