Nọ́ḿbà 35:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tàbí tí ènìyàn bá mú ohun èlò igi ní ọwọ́ ọ rẹ̀ tí ó sì lẹ̀ ẹ́ pa ènìyàn, tí ó sì fi lu ènìyàn, tí ó sì kú, apànìyàn ni; pípa ní a ó pa apànìyàn náà.

Nọ́ḿbà 35

Nọ́ḿbà 35:15-28