Nọ́ḿbà 34:28-29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

28. Pédàhẹ́lì ọmọ Ámíhúdì,olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Náfitalì.”

29. Èyí ni àwọn ẹni tí Olúwa yàn láti pín ogún náà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ilẹ̀ Kénánì.

Nọ́ḿbà 34