Nọ́ḿbà 34:22-26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

22. Búkì ọmọ Jógílì,láti ẹ̀yà olórí àwọn ọmọ Dánì;

23. Háníélì ọmọ Éfódù,láti ẹ̀yà Mánásè, olórí àwọn ọmọ Jóṣẹ́fù,

24. Kémúélì ọmọ Ṣífílánì,olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ, Éfúráímù, ọmọ Jóṣẹ́fù;

25. Élísáfánì ọmọ Pánákì,olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Ṣébúlunì;

26. Pátíélì ọmọ Ásánì,olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísákárì;

Nọ́ḿbà 34